Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadáyà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí àwọn olè tọ̀ ọ́ wá,Bí àwọn ọlọ́sà ní òru,Áà! Irú ìparun wo ló dúró dè ọ́:ṣé wọn kò jalè tó bí wọ́n ti fẹ́?Bí àwọn tí ń ká èso àjàrà tọ̀ ọ́ wá,ṣé wọn kò ni fi èésẹ́ èso àjàrà díẹ̀ sílẹ̀?

Ka pipe ipin Ọbadáyà 1

Wo Ọbadáyà 1:5 ni o tọ