Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadáyà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìwọ tilẹ̀ gbé ara rẹ ga bí ẹyẹ idì,Bí ìwọ tilẹ̀ tẹ́ ìtẹ́ rẹ sí àárin àwọn ìràwọ̀,Láti ibẹ̀ ni èmi yóò ti sọ̀ ọ kalẹ̀,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Ọbadáyà 1

Wo Ọbadáyà 1:4 ni o tọ