Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadáyà 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kì bá tí fi ojú kéré arákùnrin rẹ,ní àkókò ìbànújẹ́ rẹ̀ìwọ kì bá tí yọ̀ lórí àwọn ọmọ Júdà,ní ọjọ́ ìparun wọnìwọ kì bá tí gbéraga púpọ̀ní ọjọ́ wàhálà wọn.

Ka pipe ipin Ọbadáyà 1

Wo Ọbadáyà 1:12 ni o tọ