Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadáyà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ tí ìwọ dúró ní apákan,ní ọjọ́ tí àlejò kó ogún rẹ lọ,tí àwọn àjèjì sì wọ ibodè rẹtí wọ́n sì sẹ́ kèké lórí Jérúsálẹ́mù,ìwọ náà wà bí ọ̀kan nínú wọn.

Ka pipe ipin Ọbadáyà 1

Wo Ọbadáyà 1:11 ni o tọ