Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 8:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn èyí àwọn ọmọ Léfì lọ sínú àgọ́ ìpàdé láti lọ máa ṣiṣẹ́ wọn lábẹ́ àbojútó Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀. Wọ́n ṣe fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:22 ni o tọ