Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Iṣẹ́ Élíásárì ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà ni ṣíṣe àmójútó òróró fìtílà, tùràrí dídùn, ẹbọ ohun jíjẹ ìgbà gbogbo àti òróró ìtasórí: Kí ó jẹ́ alábojútó gbogbo ohun tó jẹ mọ́ àgọ́ àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀, pẹ̀lú gbogbo ohun èèlò ibi mímọ́.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:16 ni o tọ