Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 4:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lẹ́yìn tí Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ ti parí bíbo ibi mímọ́ àti gbogbo ohun èèlò ibi mímọ́, nígbà tí àgọ́ bá sì ṣetán láti tẹ̀ṣíwájú, kí àwọn ọmọ Kóhátì bọ́ ṣíwájú láti gbé e, ṣùgbọ́n wọn kò gbọdọ̀ fọwọ́ kan ohun mímọ́ kankan, bí wọ́n bá ṣe bẹ́ẹ̀ wọn ó kú. Àwọn ọmọ Kóhátì ni yóò gbé gbogbo ohun tó wà nínú Àgọ́ Ìpàdé.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:15 ni o tọ