Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 36:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọdún Júbélì àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá dé, a ó pa ogún wọn pọ̀ mọ́ ẹ̀yà tí wọ́n fẹ́ wọn sí, a ó sì gba ogún ẹ̀yà wọn kúrò lọ́wọ́ babańlá wọn.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 36

Wo Nọ́ḿbà 36:4 ni o tọ