Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 36:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wàyí, tí wọn bá fẹ́ ọkùnrin láti ẹ̀yà Ísírẹ́lì mìíràn; nígbà náà a ó gba ogún un wọn kúrò nínú ogún ìran wa, a ó sì fi kún ogún ẹ̀yà tí a fẹ́ wọn sí. Bẹ́ẹ̀ ni a ó sì gbàá kúrò nínú ìpín ilẹ̀ ogún ti wa.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 36

Wo Nọ́ḿbà 36:3 ni o tọ