Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 28:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àfikún ọrẹ ohun mímu rẹ gbọdọ̀ jẹ́ ìdámẹ́rin ti hínì dídé omi mímu tí ó kan pẹ̀lú ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀dọ́ àgùntàn. Da ẹbọ mímu náà síta sí Olúwa ní ibi mímọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 28

Wo Nọ́ḿbà 28:7 ni o tọ