Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 28:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pèsè ọ̀dọ́ àgùntàn kejì ní àfẹ̀mọ̀júmọ́, pẹ̀lú oríṣìí ẹbọ ohun jíjẹ àti ẹbọ ohun mímu èyí tí ó pèsè ní òwúrọ̀, èyí ni ẹbọ tí a fi iná ṣe, olóòrùn dídùn sí Olúwa.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 28

Wo Nọ́ḿbà 28:8 ni o tọ