Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 28:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ẹbọ sísun gbogbo ìgbà tí a fi lẹ́lẹ̀ ní òkè Sínáì gẹ́gẹ́ bí olóòrùn dídùn ẹbọ tí a fi iná sun fún Olúwa pẹ̀lú iná.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 28

Wo Nọ́ḿbà 28:6 ni o tọ