Ọmọbìnrin Ṣélóféhátì ọmọ Héférì, ọmọ Gílíádì, ọmọ Mákírì ọmọ Mánásè tó jẹ́ ìdílé Mánásè, ọmọ Jósẹ́fù wá. Orúkọ àwọn ọmọbìnrin náà ni Málà, Nóà, Hógílà, Mílíkà àti Tásà.