Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àwọn ọmọkùnrin Élíábù ni Némúélì àti Dátanì àti Ábírámù. Èyí ni Dátanì àti Ábírámù náà tí wọ́n ní òkìkí nínú ìjọ tí ó jẹ́ ọlọ̀tẹ̀ sí Mósè àti Árónì tí ó sì wà lára àwọn ẹgbẹ́ Kórà nígbà tí wọ́n bá Olúwa jà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 26

Wo Nọ́ḿbà 26:9 ni o tọ