Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ sì la ẹnu rẹ̀, ó sì gbé wọn mì pọ̀ pẹ̀lú Kórà, nígbà tí ẹgbẹ́ rẹ̀ kú níbi tí iná ti run àwọn àádọ́tàlérúgba ọkùnrin (250). Tí wọ́n sì di àmì ìkìlọ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 26

Wo Nọ́ḿbà 26:10 ni o tọ