Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 24:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọlọ́run mú wọn jáde láti Éjíbítì wá;wọ́n ní agbára gẹ́gẹ́ bí i ti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.Wọ́n jẹ orílẹ̀ èdè run,wọ́n fọ́ egungun wọn sí wẹ́wẹ́;wọ́n fi idà wọn gún wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 24

Wo Nọ́ḿbà 24:8 ni o tọ