Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tẹríba ó sì dùbúlẹ̀ bí kìnnìún,bí abo kìnnìún: ta ni ó gbọdọ̀ jí wọn?“Ìbùkún ni fún ẹni tí ó bùkún fún ọ,kí ìfibú jẹ́ ti ẹni tí ó fi ọ́ bú!”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 24

Wo Nọ́ḿbà 24:9 ni o tọ