Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 24:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi yóò sàn láti inú garawa:èso wọn yóò ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi.“Ọba wọn yóò ga ju Ágágì lọ;ìjọba wọn yóò di gbígbéga.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 24

Wo Nọ́ḿbà 24:7 ni o tọ