Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 24:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gẹ́gẹ́ bí àfonífojì tí ó tàn jáde,gẹ́gẹ́ bí ọgbà tí ó wà ní ẹ̀bá odò ńlá,gẹ́gẹ́ bí igi aloe tí Olúwa gbìn,gẹ́gẹ́ bí igi òpépé tí ó wà lẹ́bá odò.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 24

Wo Nọ́ḿbà 24:6 ni o tọ