Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún Árónì pé, “O kò ní ní ogún nínú ilẹ̀ wọn bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò ní ní ìpín láàrin wọn, Èmi ni ìpín àti ogún rẹ láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 18

Wo Nọ́ḿbà 18:20 ni o tọ