Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 18:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohunkóhun tí a bá ti yà sọ́tọ̀ nínú ọrẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tí wọ́n mú wá fún Olúwa ni mo fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin gẹ́gẹ́ bí ìpín rẹ tí yóò máa ṣe déédé. Ó jẹ́ májẹ̀mú iyọ̀ láéláé níwájú Olúwa fún ìwọ àti ọmọ rẹ.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 18

Wo Nọ́ḿbà 18:19 ni o tọ