Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:37-39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Olúwa sì kọlu àwọn ọkùnrin tó mú ìròyìn búburú wá nípa ilẹ̀ náà, àjàkálẹ̀-àrùn sì pa wọ́n níwájú Olúwa.

38. Nínú gbogbo àwọn tó lọ yẹ ilẹ̀ náà wò, Jóṣúà ọmọ Núnì àti Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ló yè é.

39. Nígbà tí Mósè sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n sì sunkún gidigdidi.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14