Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì kọlu àwọn ọkùnrin tó mú ìròyìn búburú wá nípa ilẹ̀ náà, àjàkálẹ̀-àrùn sì pa wọ́n níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:37 ni o tọ