Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi, Olúwa, lo sọ bẹ́ẹ̀; Èmi ó sì ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí sí ìjọ ènìyàn búburú yìí tí wọ́n kóra wọn jọ lòdì sí mi. Nínú ihà yìí ni òpin yóò dé bá wọn, ibẹ̀ ni wọn yóò kú sí.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:35 ni o tọ