Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ogójì ọdún èyí jẹ́ ọdún kan fún ọjọ́ kọ̀ọ̀kan nínú ogójì ọjọ́ tí ẹ fi yẹ ilẹ̀ náà wò ẹ̀yin ó sì jìyà fún ẹ̀ṣẹ̀ yín, ẹ ó sì mọ bí ó ti rí láti lòdì sí mi.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:34 ni o tọ