Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 1:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dípò èyí yan àwọn ọmọ Léfì láti jẹ́ alábojútó àgọ́. Ẹrí, lórí gbogbo ohun èlò àti ohun gbogbo tó jẹ́ ti àgọ́ ẹ̀rí. Àwọn ni yóò máa gbé àgọ́ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, wọn ó máa mójú tó o, kí wọn ó sì máa pàgọ́ yí i ká.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:50 ni o tọ