Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 8:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Akọ̀wé Ẹ́sírà dìde dúró lórí i pẹpẹ ìdúrólé tí a fi igi kàn fún ètò yìí. Ní ẹ̀gbẹ́ẹ rẹ̀ ọ̀tún ni Mátítayà, Ṣémà, Ánáyà, Úráyà, Hílíkáyà àti Máṣéíyà gbé dúró sí, ní ẹ̀gbẹ́ òsìi rẹ̀ ní Pédáíyà, Míṣíhẹ́lì, Málíkíjà, Hásúmù, Háṣábádánà, Ṣekaráyà àti Mésúlámù dúró sí.

Ka pipe ipin Nehemáyà 8

Wo Nehemáyà 8:4 ni o tọ