Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kà á sókè láti òwúrọ̀ títí di ọ̀sán (bí agogo méjìlá) bí ó ti kọjú sí ìta ní iwájú Ibodè-Omi ní ojú u gbogbo ọkùnrin, obìnrin àti àwọn ènìyàn tó kù tí òye le è yé tí wọ́n wà níbẹ̀. Gbogbo ènìyàn sì fetísílẹ̀ sí ìwé òfin náà pẹ̀lú ìfarabalẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemáyà 8

Wo Nehemáyà 8:3 ni o tọ