Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 6:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí a kọ sínú un rẹ̀ pé:“A ròyìn rẹ láàárin àwọn orílẹ̀ èdè—Géṣémù sì sọ pé, òtítọ́ ni, pé—ìwọ àti àwọn Júù ń gbérò láti ṣọ̀tẹ̀, nítorí náà ni ẹ ṣe ń mọ odi. Síwájú sí i, gẹ́gẹ́ bí ìròyìn yìí, ìwọ sì ń gbérò láti di ọba wọn

Ka pipe ipin Nehemáyà 6

Wo Nehemáyà 6:6 ni o tọ