Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà kárùn-ún, Sáńbálátì rán ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ sí mi pẹ̀lú irú iṣẹ́ kan náà, lẹ́tà kan tí a kò fi sínú apo ìwé wà ní ọwọ́ọ rẹ̀

Ka pipe ipin Nehemáyà 6

Wo Nehemáyà 6:5 ni o tọ