Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 13:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kìí ha á ṣe àwọn ìgbéyàwó bí irú èyí ni ọba Sólómónì fi dá ẹ̀ṣẹ̀? Láàrin àwọn orìlẹ̀ èdè, kò sí ọba kan bí i tirẹ̀. Ọlọ́run rẹ̀ féràn rẹ̀, Ọlọ́run sì fi jẹ ọba lóríi gbogbo Ísírẹ́lì, ṣùgbọ́n àwọn obìnrin àjòjì ti sọ ọ́ sínú òfin ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemáyà 13

Wo Nehemáyà 13:26 ni o tọ