Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 13:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo bá wọn wí mo sì gégùn-ún lé wọn lórí. Mo lu àwọn ènìyàn díẹ̀ nínú un wọn mo sì fa irun oríi wọn tu. Mo mú kí wọn búra ní orúkọ Ọlọ́run, kí wọn wí pé, “Ẹ̀yin kì yóò fi àwọn ọmọbìnrin wọn fún àwọn ọmọkùnrin yín ní ìyàwó tàbí fún ẹ̀yin tìkáara yín.

Ka pipe ipin Nehemáyà 13

Wo Nehemáyà 13:25 ni o tọ