Nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn panṣágààgbèrè tí ó rójú rere gbà,Iyá àjẹ́ tí ó sọ́ àwọn orilẹ̀-èdè di ẹrúnipa àgbèrè rẹ̀àti àwọn ìdílé nipa ìṣe àjẹ́ rẹ̀.