“Èmi dojú kọ ọ́,” ni Olúwa awọn ọmọ ogun wí.“Èmi ó si ká aṣọ ìtẹ́lẹ̀dì rẹ ní ojú rẹ,Èmi yóò sì fi ìhòòhò rẹ̀ han àwọn orílẹ̀-èdèàti ìtìjú rẹ̀ han àwọn ilẹ̀ ọba.