Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 3:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ológun orí ẹṣin ń fi ìgbónáraju ìdà wọn mọ̀nàmọ̀nàọ̀kọ̀ rẹ̀ ti ń dán yanran sí òkè!Ọ̀pọ̀lọpọ̀ si ní àwọn ẹni tí a pa,àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkú;òkú kò si ni òpin;àwọn ènìyàn sì ń kọsẹ̀ lára àwọn òkú.

Ka pipe ipin Náhúmù 3

Wo Náhúmù 3:3 ni o tọ