Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 2:12-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Kìnnìún pàápàá tẹ́rù fún àwọn ọmọ rẹ̀,ó sì fún-un ní ọ́rùn pa fún àwọn abo kìnnìún rẹ̀,Ó sì fi ohun pípa kún ibùgbé rẹ̀àti ihò rẹ̀ fún ohun ọdẹ.

13. “Kíyèsíi èmi dojú kọ ọ́,”ni Olúwa awọn ọmọ ogun wí.“Èmi yóò sì fi kẹ̀kẹ́ rẹ̀ wọ̀n-ọn-nì jóná nínú èéfín,idà yóò sì jẹ ọmọ kìnnìún rẹ̀ wọ̀n-ọn-nì run.Èmi yóò sì ké ohun ọdẹ rẹ kúrò lórí ilẹ̀ ayéOhùn awọn òjíṣẹ́ rẹni a kì yóò sì tán gbọ́ mọ́.”

Ka pipe ipin Náhúmù 2