Níbo ni ihò àwọn kìnnìún wààti ibi ìjẹun àwọn ọmọ kìnnìún,níbi tí kìnnìún, àní abo kìnnìún ti ń rìn,àti ọmọ kìnnìún, láìsí ohun ìbẹ̀rù