Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kíyèsíi èmi dojú kọ ọ́,”ni Olúwa awọn ọmọ ogun wí.“Èmi yóò sì fi kẹ̀kẹ́ rẹ̀ wọ̀n-ọn-nì jóná nínú èéfín,idà yóò sì jẹ ọmọ kìnnìún rẹ̀ wọ̀n-ọn-nì run.Èmi yóò sì ké ohun ọdẹ rẹ kúrò lórí ilẹ̀ ayéOhùn awọn òjíṣẹ́ rẹni a kì yóò sì tán gbọ́ mọ́.”

Ka pipe ipin Náhúmù 2

Wo Náhúmù 2:13 ni o tọ