Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Míkà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, Olúwa wí pé:“Èmi ń gbérò ibi sí àwọn ìdílé wọ̀nyí,nínú èyí tí wọn kì yóò le è gba ara wọn là.Ìwọ kì yóò sì lè máa rìn ní ìgbéraga mọ́,nítorí yóò jẹ́ àkókò ibi.

Ka pipe ipin Míkà 2

Wo Míkà 2:3 ni o tọ