Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Míkà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà ni ẹnìkan yóò fi ọ́ ṣe ẹlẹ́yà;wọn yóò sì pohùn réré ẹkún kíkorò pé:‘Ní kíkó a ti kó wọn tán; Olúwa ti pín ohun ìní àwọn ènìyàn mi;Ó ti mú un kúrò lọ́dọ̀ mi!Ó fi oko wa lé àwọn ọlọ̀tẹ̀ lọ́wọ́.’ ”

Ka pipe ipin Míkà 2

Wo Míkà 2:4 ni o tọ