Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Míkà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì ń ṣe ojúkòkòrò oko, wọ́n sì fi agbára wọn gbà wọ́n,àti àwọn ilé, wọ́n sì gbà wọ́n.Wọ́n sì ni ènìyàn àti ilẹ̀ rẹ̀ láraàni ènìyàn àti ohun ìní rẹ̀.

Ka pipe ipin Míkà 2

Wo Míkà 2:2 ni o tọ