Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo kórìíra ìkọ̀sílẹ̀,” ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, “bẹ́ẹ̀ ni mo kóríra kí èníyàn máa fi ipá bó ara rẹ̀ àti pẹ̀lú asọ rẹ̀,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.Nítorí náà ẹ sọ́ ẹ̀mí yín, kí ẹ má se hùwà ẹ̀tàn.

Ka pipe ipin Málákì 2

Wo Málákì 2:16 ni o tọ