Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ti fi ọ̀rọ̀ yin dá Olúwa ní agara.Ṣùgbọ́n ẹ̀yin béèré pé, “Nínú kín ni àwa fi dá a lágara?”Nígbà tí ẹ̀yìn wí pé, “Gbogbo ẹni tí ó ṣe ibi, rere ni níwájú Olúwa, inú rẹ̀ sì dùn sí wọn,” tabi “Níbo ni Ọlọ́run ìdájọ́ gbé wà?”

Ka pipe ipin Málákì 2

Wo Málákì 2:17 ni o tọ