Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run kò hà ti ṣe wọ́n ní ọ̀kan? Ni ara àti ni ẹ̀mí tirẹ̀ ni. Èéṣe tí Ọlọ́run da yín l'ọ́kàn? Kí òun bá à lè wá irú ọmọ bí ti Ọlọ́run. Nítorí náà, ẹ tọ́jú ẹ̀mí yín, ẹ má sì ṣe hùwà ẹ̀tàn sí aya èwe yín;

Ka pipe ipin Málákì 2

Wo Málákì 2:15 ni o tọ