Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Tàbí bí ó bá fọwọ́ kan ohun àìmọ́ ti ènìyàn-ohunkóhun tó lè mú ni di aláìmọ́-bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹni náà kò mọ̀, nígbà tí ó bá mọ̀ nípa rẹ̀ yóò jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Léfítíkù 5

Wo Léfítíkù 5:3 ni o tọ