Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Tàbí bí ẹnìkan bá fọwọ́ kan ohun tí a kà sí àìmọ́ yálà òkú ẹranko aláìmọ́ tàbí òkú ẹran ọ̀sìn aláìmọ́ tàbí òkú ẹ̀dá yòówù tó ń rìn lórí ilẹ̀ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹni náà kò mọ̀, ó ti di aláìmọ́, ó sì ti jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Léfítíkù 5

Wo Léfítíkù 5:2 ni o tọ