Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Tàbí bí ẹni kan bá búra láti ṣe ohun kan láì ronú lé e lórí, yálà ohun tó dára tàbí ohun búburú, nínú ọ̀rọ̀ yòówù tó ti búra láì kíyèsí ara, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, kò mọ̀ nípa rẹ̀ tẹ́lẹ̀, bí ó ti wù kó rí, nígbà tó bá mọ̀ yóò jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Léfítíkù 5

Wo Léfítíkù 5:4 ni o tọ