Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 24:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tò wọ́n sí ọ̀nà ìlà méjì, mẹ́fàmẹ́fà ní ìlà kọ̀ọ̀kan lórí tábìlì tí a fi ojúlówó gòólù bọ̀. Èyí tí ó wà níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 24

Wo Léfítíkù 24:6 ni o tọ