Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 24:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú ìyẹ̀fun dáradára, kí o sì ṣe ìṣù àkàrà méjìlá, kí o lo ìdáméjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n ẹfà (èyí jẹ́ lítà mẹ́rin ààbọ̀) fún ìṣù kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Léfítíkù 24

Wo Léfítíkù 24:5 ni o tọ