Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbọdọ̀ fi wọ́n rú ẹbọ níwájú Olúwa láti ṣe ètùtù fún obìnrin náà lẹ́yìn náà ni yóò di mímọ́ kúrò nínú ìsun ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.“ ‘Ìwọ̀nyí ni àwọn ìlànà fún obìnrin tí ó bá bí ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin.

Ka pipe ipin Léfítíkù 12

Wo Léfítíkù 12:7 ni o tọ